Our Anthem

Ise wa fun ile wa
Fun Ile Ibi Wa
Ka gbee ga, ka gbee ga
Ka gbee ga f'aye ri

Igbagbo wa ni pe
Bati beru la bomo
Ka sise, ka sise
Ka sise ka j'ola

Isokan at'ominira
Ni ke je ka maa lepa
Tesiwaju f'opo ire
At'ohun to dara

Omo Oodua dide
Bo s'ipo eto re
Iwo ni imole
Gbogbo Adulawo